Awọn abọ-ọrọ õrõnyõn ti ko se gbàgbé
 • Bah (ba’ / boh / bain / buh / ban / bo)

  Le tunmọ si ayo, ibanu je, iyalenu ati eyikeyi miiran inú, nigba ti o lo pẹlu deede atenumọ. Ti o ba kọ lati lo Bah, o le ri se laisi wàhálà .

  Homem Polar Apere: Bah, Polar yi dara gan o. Arrow Homem Polar
 • TCHÊ (tch’et)

  Ki o to sö "iya" , taura wí pé "tchê". O je gege bi atenumọ si ohun ti o ti so, Nitori yi lo fi jẹ ohun alumọni ni gbogbo gbolohun awọn gaucho, gbolohun yi le han ni ibẹrẹ tabi opin.

  Homens Polar Apere: Tchê, ma ṣe gbagbe Polar mi . Arrow
  Homens Polar
Ìwé ìkójô ôrô ìpìlê Voltar Linguajar que é quase um dialeto. Ver dicionário bagual All
A
 • Abobado (aw-bo’-baw-dow)

  ômôdébí èwe, wèrè, eniyan ti o ko ma n sọ isọkusọ .

 • Afudê (a’-foo-the)

  Ti o dara.

  Search
  Afudê - Legal, maneiro, massa.
 • Amorcegar (aw-mor-say-gar)

  Ko ṣiṣẹ. Eniyan ti o ko fe ṣiṣẹ ..

 • Aprochegar (aw-mor-say-gar)

  Se a sunmọ, darapọ.

 • Atochar (a’-foo-the)

  pa irọ, fun pọ.

B
 • Bagual

  Eniyan ti o nígboyà tabi olomoge.

 • Baita

  Nla, tobi.

 • Barbaridade

  Ṣàìbögbönmu, iya lenu, ìse buruko.

 • Bruxo

  Ọrẹ, Obeni.

 • Bueno

  Dara.

C
 • Cancha

  Ibi lati ṣe rẹ tabi paapa lati ka iwe.

 • Chimarrão

  Ohun mimu keji ni ipinle ti o dara ju , se ṣe pẹlu ewe mate ati omi to gbona yoo wa ninu abó kan ti won pe ni porongo.

  Search
  Chimarrão
 • Chimia

  Onje aládùn.

 • Cuiudo

  Olomoge.

 • Cusco

  Aja kekere , ije-lasan. Bakanna bi guaipeca.

  Search
  Cusco
E
 • Entrevero

  Adalu, idaru, ìdàrúdàpö, awon eniyan, eranko tabi awọn nkan.

 • Esgualepado

  Eni idoti,.

F
 • Faceiro

  Lálàfiàníroran, inúdídùn, onígberaga.

  Search
  Faceiro
G
 • Guasca

  Álàimo tabi eniyan ti o nígboyà.

L
 • Lagartear

  Sun tabi joko ni ilenle ninu oorun ọjọ ti o tutu gan.

M
 • Mazá

  Itọkasi ohun ta feran gan.

O
 • Oigalê

  Iferan tabi iyalenu.

  Search
  Oigale
P
 • Peleia

  Ìja, ifarakanra, ija laarin ologun.

  Search
  Peleia
 • Pila

  Owo, ọkan iye.

 • Prenda

  Iyawo gaucho. obinrin ti o lẹwa.

  Search
  Prenda
 • Preza

  Ti o dara lati wo.

T
 • Tri

  Rọpo ọrọ "gidigidi" tabe “gan”, sugbon o tun le tumọ si dara.

 • Trovar

  Idaniloju ; fi ife han si ẹnikan.

 • Tu

  Iwo.

V
 • Varzeano

  Eni ti ko mo gba bọọlu, arínifín.

X
 • Xucro

  Eni álàini isesi awujo. Itiju.